
ILÉ ÌGBÌMỌ̀ AṢÒFIN ÌPÍNLẸ̀ ÈKÓ: ÌDÚPẸ́
Olùdarí, Aṣòfin Mudashiru Àjàyí Ọbásá, àwọn Olóyè Ilé, Ọmọ-ẹgbẹ́ Aṣòfin, Àwọn Alákòóso àti Òṣìṣẹ́ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ gbogbo àwọn Gómìnà, Ọba Alayélúwà, Ọ̀tọ̀kùlú àti àwọn ẹni bí ẹni tí a pè tí wọ́n jẹ́ ìpè wá ní àsìkò Ìpàdé Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ tí a ṣe ní Ọjọ́bọ, Ọjọ́ Kejì oṣù Kẹfà, ọdún Ẹgbàálémẹ́ríndínlógún pẹ̀lú àkọ́lé: “Mímú Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá Ní Kàn-ń-pá Ní Àwọn Iléèwé Ìjọba Àti Aládàáni Ní Ìpínlẹ̀ Èkó.”
A gbé òṣùbà ràbàǹdà fún un yín fún àtìlẹ́yìn, àmọ̀ràn àti ipa ribiribi tí ẹ kó ní àsìkò ètò náà.
Ní pàtàkì jùlọ, ọpẹ́ àtinúwá wa lọ sí ọ̀dọ àwọn ènìyàn jàn-ǹ-kàn jàn-ǹ-kàn wọ̀nyí:
ü Ọlọ́lá-jùlọ Ọ̀gbẹ́ni Rauf Adésọjì Arẹ́gbẹ́ṣọlá (Gómìnà ti Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun)
ü Ọba Ẹnìtán Adéyẹyè Ògúnwùsì (Ọ̀ọ̀ni ti Ilẹ̀ Ifẹ̀)
ü Baṣọ̀run Muyiwa Ọládiípọ̀ (Aṣojú Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ògùn)
ü Àwọn Ọmọ-ẹgbẹ́ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Ògùn àti Ọ̀ṣun
ü Aṣòfin Jókòtọ́lá Pẹ̀lúmi (Olùdarí tẹ́lẹ̀ rí ní Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó)
ü Àwọn Ọmọ-ẹgbẹ́ Aṣòfin tẹ́lẹ̀ rí ní Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó
ü Aṣòfin-àgbà Ọlọ́runḿbẹ Mamora
ü Alága àti àwọn Kọmíṣánnà Ìgbìmọ̀ Amójútó Ọ̀rọ̀ àwọn Òṣìṣẹ́ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Àkànní Igue
ü Alàgbà Peter Fátómilọ́lá
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Olú Akéwúṣọlá
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Orímóògùnjẹ́
ü Ọ̀gbẹ́ni Olúṣọlá Macaulay (Aṣojú Àjọ UNESCO)
ü Àwọn Olóyè Onífìlà Funfun
ü Olóyè Ìdòwú Ọbásá
ü Lánre Aya Hassan
ü Ẹgbẹ́ Ìgbìmọ̀ Ọ̀dọ́ Ilẹ̀ Yorùbá
ü Iléeṣẹ́ Aṣèwétà Aqua Green Limited
ü Gbogbo Ọ̀jọ̀gbọ́n, Ọ̀mọ̀wé, Iléeṣẹ́, Oníròyìn, Akẹ́kọ̀ọ́, àti ènìyàn àtàtà yòókù tí a ò dárúkọ.
|
ü Ọlọ́lá-jùlọ, Bọ́láńlé Aya Aḿbọ̀dé (Aya Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó)
ü Ọba Làmídì Adéyẹmí (Aláàfin ti Ìlú Ọ̀yọ́)
ü Aṣòfin Suraj Ìṣọ̀lá Adékúnbi (Olùdarí, Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Ògùn)
ü Dókítà Samuel Adéjàre (Kọmíṣánnà Ètò Àyíká ní Ìpínlẹ̀ Èkó) ü Ọ̀gbẹ́ni Kehinde Joseph (Olùdámọ̀ràn Pàtàkì sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó lóri Ọ̀rọ̀ Ìdásí Aráàlú)
ü Àwọn Ọmọ-ẹgbẹ́ Akọ̀wé-àgbà àti Olùkọ́ni-àgbà ní Ìpínlẹ̀ Èkó
ü Aṣòfin Àbáyọ̀mí Kínyọmí
ü Aláíge ti Orílé Agége
ü Àlájì Mùtíù Àrẹ
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Akínwùmí Ìṣọ̀lá
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Adéníyì Harrison
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Akinloyè Òjó (Yunifásitì ti Georgia)
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Fákinlèdé K.J.
ü Ọ̀jọ́gbọ́n Ajíbóyè O.J.
ü Ọ̀mọ̀wé Ìlọ̀rí J.F.
ü Aṣojú Àjọ UNICEF
ü Àwọn Alága Ìjọba Ìbílẹ̀ àti Agbègbè Ìdàgbàsókè Ìjọba Ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó
ü Alàgbà Túndé Kèlání
ü Àwọn Báálẹ̀ láti Ìjọba Ìbílẹ̀ Agége
|
ü Ọlọ́lá-jùlọ, Ọ̀mọ̀wé Olúrántí Adébùlé (Igbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó)
ü Ọba Rilwan Àrẹ̀mú Akiolú (Ọba ti Ìlú Èkó)
ü Aṣojú Alága Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC ní Ìpínlẹ̀ Èkó
ü Aṣòfin-àgbà Ọlábìyì Dúrójayé
ü Aṣòfin Ọláwálé Oshun
ü Ọba Kàbírù Agbábíàká (Ọsọ́lọ̀ ti Ìsọlọ̀)
ü Àlájì S.A. Sùnmọ́là
ü Falilat Aya Ọbásá àti gbogbo àwọn Aya Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Dúró Adélékè
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Sophie Olúwọlé
ü Àlájì Kareem Adépọ̀jù
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Dípọ̀ Gbénró
ü Ọ̀jọ̀gbọ́n Abísógun Leigh
ü Ọ̀mọ̀wé Oyèwálé A.S.
ü Àwọn Alákòóso láti Iléeṣẹ́ Ìjọba àti Iléeṣẹ́ Aṣojú Ìjọba
ü Ọmọọba Jídé Kòsọ́kọ́
ü Ọ̀túnba Adébáyọ̀ Sàlámì
ü Ẹgbẹ́ àwọn Akọ́mọlédè àti Àṣà Yorùbá
ü Ilé Ìfowópamọ́ WEMA
ü Iléeṣẹ́ Aṣèwétà Learn Africa
ü Ẹgbẹ́ àwọn Olùkọ́-àgbà ní Iléèwé Sẹ́kọ́ǹdìrì ní Ìpínlẹ̀ Èkó
|
Ẹ ṢÉ PÚPỌ̀. OÒDUÀ Á GBÈ WÁ O!
|
AṢÒFIN MUDASHIRU ÀJÀYÍ ỌBÁSÁ
OLÙDARÍ, ILÉ ÌGBÌMỌ̀ AṢÒFIN ÌPÍNLẸ̀ ÈKÓ
ILÉ ÌGBÌMỌ̀ AṢÒFIN ÌPÍNLẸ̀ ÈKÓ………………………………………..………ó tayọ ìgbéléwọ̀n àṣeyọrí.
Write a Comment