OONI ILE IFE, OLOWO EKO ATI ALAAFIN TI ILU OYO NI APERO LORI KIKO EDE YORUBA

Awon Oba Alayeluwa, Alase Ekeji Orisa naa pejo po si ayeye akiyesi lori kiko ede yoruba ni awon ile eko ipinle eko. Ni ijoko lati apa osi: Ọọ̀ni ti Ilè-Ifẹ̀, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Oojaja 1), Olowo Eko, Oba Rilwan Babatunde Osuolale Aremu Akiolu ati Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi III.

Write a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *